Gospel MusicLyricsTrending

DOWNLOAD Eni Giga By Kemsyl Music [Mp3+Lyrics Song]

Download Eni Giga By Kemsyl Music. Sensational African Singer Kemsyl Music releases Her Song Title, Eni Giga. download below.

African award winning international Gospel music minister Kemsyl Music Releases Her New single titled “Eni Giga“.

Kindly, Get This Song And Be Bless With It. Download, Stream, Share And Subscribe. Thanks.

DOWNLOAD MP3

LYRICS

A tẹ́ itẹ́ kan li ọrun, ẹnikan si joko lori itẹ́ na.
Ẹniti o joko na dabi okuta jaspi ati sardi ni wiwo:
oṣumare si ta yi itẹ́ na ká,
o dabi okuta smaragdu ni wiwo.
Yi itẹ́ na ká si ni itẹ́ mẹrinlelogun:
ati lori awọn itẹ́ na mo ri awọn àgba mẹrinlelogun joko,
ti a wọ̀ li aṣọ àlà;
ade wura si wà li ori wọn.
Ati lati ibi itẹ́ na ni mànamána ati ãrá ati ohùn ti jade wá:
fitila iná meje si ntàn nibẹ̀ niwaju itẹ́ na ti iṣe Ẹmi meje ti Ọlọrun.
Ati niwaju itẹ́ na si ni okun bi digí, o dabi kristali:
li arin itẹ́ na, ati yi itẹ́ na ká, li ẹda alãye mẹrin ti o kún fun oju niwaju ati lẹhin.
Awọn ẹda alaye mẹrin na, kò si simi li ọsán ati li oru,

Lead vocal: Oluwa Olorun Olódùmarè

Lead vocal: (once)
Eni giga Julo Oun lo lorun o o o oo
Eni giga julo Oun Lolorun o
Eni giga Julo Oun lo lorun o o o
Eni giga julo Oun Lolorun o
Imole ta ko le beju wo
To tin tan titi aiyeraye o o
Eni giga julo oun lolorun o

(Oun lolorun wa)

Chorus
Eni giga Julo Oun lo lorun o o o (Oun nikan ni laiye, lorun, eni giga ni)
Eni giga julo Oun Lolorun
Imole ta ko le beju wo (lai lai)
To tin tan titi aiyeraye o o (aiyeraiye aiyeraye ni…….. oun lolorun o)
Eni giga julo oun lolorun o

Verse 1:
Igbeke le wa Ko si ninu eniyan ooo
Igbekele wa, ninu Olorun ni e e e
O da le lori oun tooje ati ni’bujoko too gbe wa o ooo
Eni giga Julo yen oun lolorun

Lead call to chorus (oun lo lorun wa)

Chorus
Eni giga Julo Oun lo lorun o o o (Oun nikan ni laiye, lorun, eni giga ni)
Eni giga julo Oun Lolorun
Imole ta ko le beju wo (lai lai)
To tin tan titi aiyeraye o o (aiyeraiye aiyeraye ni……oun lolorun o)
Eni giga julo oun lolorun o

Verse 2
Ibujoko Re, Olodumare O ga pupo oo
O re wa ju,
Mimo mimo ni
Ogigi Imole lo yio ka
Awon Ogun Olorun Duro ni apa otun ati apa osi re
Iseti Aso igunwa re, kun nu tempili Baba mimo
Oluwa Soro, gbogbo aiye wariri niwaju re
Ni ibujoko re, Iyin o le duro o lai lai
Eni giga Julo o Oun lolorun

Lead call to Chorus (Oun nikan ni o)
Eni giga Julo Oun lo lorun o o
o (Oun nikan ni laiye, lorun eni giga ni)
Eni giga julo Oun Lolorun,
Imole ta ko le beju wo (lai lai)
To tin tan titi aiyeraye o o (aiyeraiye aiyeraye ni…… oun lolorun o)

Eni giga julo oun lolorun o

Lead call to Chorus (Oun nikan ni o)

Eni giga Julo Oun lo lorun o o o (Oun nikan ni laiye, lorun, eni giga ni)
Eni giga julo Oun Lolorun
Eni giga Julo Oun lo lorun o o o (Oun nikan ni laiye, lorun, eni giga ni)
Eni giga julo Oun Lolorun
Imole ta ko le beju wo (lai lai)
To tin tan titi aiyeraye o o (aiyeraiye aiyeraye ni…… oun lolorun o)
Eni giga julo oun lolorun o

Chant
Adagba ma paro Oye ni baba agabalagba ooooo oun lolorun oo.

Gospelconnectmedia

A Pro Blogger // Advertiser // Coach // Content Creator // Programmer // Web Design

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button *