Gospel MusicLyricsTrending

DOWNLOAD Iwo Ni By Omolola Oguntoye [Mp3+Video & Lyrics]

Download Iwo Ni By Omolola Oguntoye. Sensational African Singer Omolola Oguntoye releases Her Song Title, Iwo Ni. download below.

Stream and download below…

DOWNLOAD MP3

Social Media Handles;

Facebook: omololaoguntoye
Instagram: @ omololachristianah20

LYRICS

[Intro]
O, O, O Iwo ni
Iwo ni imole mi
Iwo ni imole mi
Iwo ni atona mi
Iwo ni olutunu mi
O,O,O Iwo ni
Eyin ni atona mi
Eyin ni imole mi
Eyin ni olutunu mi

[Chorus]
Iwo ni imole mi nigba to okunkun su
Iwo ni agbara mi nigba ti o si oluranlowo
Iwo ni imole mi, Iwo ni imole mi (2ce).

[Chorus]
Iwo ni imole mi nigba to okunkun su
Iwo ni agbara mi nigba ti o si oluranlowo
Iwo ni imole mi, Iwo ni imole mi

[Verse]
Iwo ni adurotini gbagba lojo isoro
Oba ti o dojutimi ti o fimisile fun yaje
Oba to to gbekele e e e, Iwo ni
Iwo ni olorun mi Iwo ni

[Chorus]
Iwo ni imole mi nigba to okunkun su
Iwo ni agbara mi nigba ti o si oluranlowo
Iwo ni imole mi, Iwo ni imole mi

Bridge-(Call and response)

Olutunu mi, Iwo ni
My help, my shield
Adurotini
Olugbeja omo orukan
Olorun mi
Oba ti o ko mi sile
Oba ti o fimisile
Olorun mi
Aseda mi
Oba to to gbojule
Oba ti o doju timi rara
Nigba ojo nigba erun
e, e, e eyin ni
eyin ni olorun mi
My comforter, my shield
A to gbojule
Ato foro lo

Gospelconnectmedia

A Pro Blogger // Advertiser // Coach // Content Creator // Programmer // Web Design

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button *